
Internet Explorer 9 ti Windows fun Windows 7
Apejuwe ni soki
Internet Explorer 9 ti Windows ń jẹ́ki àwọn oju-opo wẹ́ẹ̀bù rẹ tàn ki wọ́n sì ṣiṣẹ́ bíi àwọn àtòjọ-eto tiwa-n-tiwa lori PC rẹ.
Ni Oju-iwe Yii
Awọn Alaye ni Kiakia
| Orukọ Faili: | IE9-Windows7-x86-yor.exe |
| Ẹya: | 9.0.7930.16406 |
| Orisun Imọ (KB) Awọn Agbelẹkọ: | KB982861 |
| Ọjọ Igbejade: | 22/06/32 |
| ede: | Ede Yoruba |
| Iwọn Gbaa lati ayelujara: | 17.8 MB |
| Akoko ti a lero pe yoo to fun gbaa lati ayelujara: | 44 işj 56K |
|
| Yi Ede Pada: | |
Ibojuwo alakotan
Windows Internet Explorer 9 n fi àwọn oju-opo wẹ́ẹ̀bù ati àwọn àtòjọ-eto tó farajọ tó si ń ṣiṣẹ́ bíi àwọn àtòjọ-eto PC tiwa-n-tiwa nipaṣẹ̀ agbara ti Windows jíṣẹ́ funni
-
Yíyára: Internet Explorer 9 jẹ́ eyiti o fi gbogbo ara yára. Ti a ṣàgbékalẹ̀ lati ṣamulo anfani ti ẹ̀yà aridimu líle PC rẹ nipaṣẹ̀ Windows, Internet Explorer 9 ń fi àwọn ìrírí alaworan afihan tó kun fọ́fọ́ ti o yára tí o si ń danilohun bíi àwọn àtòjọ-eto tiwa-n-tiwa lori PC rẹ jíṣẹ́.
-
Ìmọ́tótó: Internet Explorer n gbájúmọ́ orí àwọn oju-opo Wẹ́ẹ̀bù ti o fẹ́ràn pẹ̀lú ìwò tó mọ́ tótó ati agbegbe ìwò to ga síi eyiti o n mu àwọn oju-opo Wẹ́ẹ̀bù to n tàn gbinrin. Àgbékalẹ̀ ti èrò inu ti kò wọ́ rárá pẹ̀lú Windows 7 ń pese iraye si ìsíra tẹ̀ kan si àwọn àtòjọ-eto Wẹ́ẹ̀bù ti a somọ́ tààrà si Pẹpẹ-iṣẹ́.
-
Tó Ṣeé Gbẹ́kẹ̀lé: Internet Explorer jẹ ọ̀nà tó ṣeé gbẹ́kẹ̀lé kan si Wẹ́ẹ̀bù nitoripe o ni akojopọ̀ ààbò agbesinu kan tó gbópọn, ìpamọ́ ati àwọn ìmọ̀-ẹ̀rọ ìṣeégbẹ́kẹ̀lé ti o ń mu ọ wà ninu aabo síi ti o sì ń jẹ́kí ìrírí ìṣàwákiri rẹ jẹ́ ailanidaduro.
-
Tí o Ṣeé lò Ninu Ọ̀pọ̀ Ẹ̀rọ: Àtìlẹyìn fun HTML5 ati àwọn gbedeke Wẹ́ẹ̀bù igbalode ti a ṣagbelẹrọ lati ṣamulo anfani ti GPU ń tumọ̀̀̀ sì pe kì í ṣe wipe iye ayipada kan náà ń ṣiṣẹ́ kaakiri Wẹ́ẹ̀bù nikan, ṣùgbọ́n o ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lu ìyára síi atipe o funni ni iriri tó kun fọ́fọ́ nipaṣẹ̀ Windows ati Internet Explorer 9.
Oke oju-iwe
Awọn Ohun ti Ẹrọ nilo lati Sişẹ
- Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti: Windows 7
-
- Windows 7
- Windows 7 pẹ̀lú Service Pack 1
- Kọ̀ǹpútà/ Olùgbéṣẹ́ṣe: Kọ̀ǹpútà pẹlú ̀olùgbéṣẹ́ṣe 233MHz tabi jù bẹ́ẹ̀ lọ (Olùgbéṣẹ́ṣe Pentium ni a gbani niyanju rẹ̀)
- Ìrántí: 512MB
- Ààyè Dísìkì Aridimu Líle:70MB
- Àfihàn: Super VGA (800 x 600) ti amaworantan oníìtẹjúmọ́ àwọ̀ to ga pẹ̀lú àwọn àwọ 256.
- Àwọn Àsomọ́ra: Modẹ́ẹ̀mù tabi ìsopọ̀ Íntánẹ́ẹ̀tì; Atọ́ka Microsoft, Atọ́kaỌlọ́pọlọ Microsoft, tabi ohun-èlò atọ́ka tó báramu.
Oke oju-iwe
Awọn Ilana
- Síra tẹ bọ́tìnnì Gba Ẹ̀dà Faili Sọ̀kalẹ̀ loju iwe yìí lati bẹ̀rẹ̀ gbigba ẹ̀dá faili náà sọ̀kalẹ̀.
- Ṣe ọ̀kan ninu àwọn àtẹ̀lé wọ̀nyí:
- Lati bẹ̀rẹ̀ ìṣagbekalẹ̀ naa loju-ẹṣẹ́, síra tẹ Ṣíi or Fi àtòjọ-eto yii ṣiṣẹ́ lati ibi tó wà lọ́wọ́lọ́wọ́.
- Lati ṣẹ̀dà faili ti a gbà sí ori kọ̀ǹpútà rẹ fun iṣagbekalẹ̀ ni igba miran, síra tẹ Ṣafipamọ́ tabi Ṣafipamọ́ àtòjọ-eto yìí si dísìkì.
Oke oju-iwe
Afinku Alaye
Ẹ̀dà faili ti a gbà sọ̀kalẹ̀ yìí wa fun Internet Explorer 9 fun Windows 7, Windows 7 SP1 nikan. Lati gba Internet Explorer 9 fun àwọn ẹ̀yà miran ti a ṣatilẹ́yin fun ti Microsoft Windows:
Oke oju-iwe
Oke oju-iwe