Office

  Thank you for downloading

  • Service Pack 3 fún Office Language Interface Pack 2007 (KB2526307)

   If your download does not start after 30 seconds, Click here
    • Àkíyèsí: Àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ IT nilati lọ sí àwọn ohun àmúṣọrọ̀ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ IT abala.

     Àwọn ìtọ́niṣọ́na ìṣàgbékalẹ̀
     Bí o bá ní Microsoft Office Language Interface Pack 2007, ẹ̀yà 32-bit, ṣe ọ̀kan ninu àwọn àtẹ̀lé wọ̀nyí:

     • Ṣe àgbékalẹ̀ Service Pack 3 fún Office Language Interface Pack 2007 (KB2526307). Láti ṣe èyìí , tẹ̀lé àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí:
      1. Gba ẹ̀dà fáìlì .exe náà sọ̀kalẹ̀ nípa sísíra tẹ̀ lori bọ́tìnnì Gba Ẹ̀dà Fáìlì Sọ̀kalẹ̀ ní òkè ojú-ìwé náà, kí o sì ṣàfipamọ́ fáìlì náà sí orí awakọ̀ díìkì líle rẹ.
      2. A gbà ọ́ niyanju lati gbé àwọn àtòjọ-ètò eyikeyii tí o n tàn lọ́wọ́ jáde kuro.

      3. Ní inú Windows Explorer, síra tẹ fáìlì .exe náà tí o ṣàfipamọ́ sí orí awakọ̀ dísìkì rẹ lẹ́ẹ̀mejì, kí o sì tẹ̀lé àwọn ìtọ́niṣọ́nà lójú agbàwòrántàn rẹ náà.


     Àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ IT
     Àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ IT tí wọn n ṣiṣẹ́ ní àwọn àyíká ti a n ṣàkóso leè wá àwọn ohun àmúṣọrọ̀ fún ṣíṣàmúlò àwọn ìṣàfikún Office ni ibi iṣẹ́ tówà lórí Office System Suites ati Ibùdó-Ìmọ̀-ẹ̀rọ Àwọn Àtòjọ-ètò.

     Gbígba ẹ̀dà fáìlì sọ̀kalẹ̀ fun ìṣàfikún yìí wànílẹ̀ nípa sísíra tẹ̀ lori bọ́tìnnì Gba Ẹ̀dà Fáìlì Sọ̀kalẹ̀ ní òkè ojú-ìwé náà. O leè síra tẹ àkópapọ̀ tí o ṣeé lò náà lẹ́ẹ̀mejì láti bẹ̀rẹ̀ ìṣàgbékalẹ̀, tabi ki o fa àwọn fáìlì ojú àtúnṣe extract the patch files (àwọn fáìlì MSP) npa lílo ìlà àṣẹ kan. Ìlà àṣẹ náà ati àwọn ìtọ́niọ́nà ni a fi si inú ìwé àpilẹ̀kọ Ibùdó Ìmọ̀ náà àwọn ìṣípòpadà ìlà Àṣẹ fún àwọn àkópapọ̀ Microsoft Self-Extractor (KB912203).

     Wo ìwé àpilẹ̀kọ Ibùdó Ìmọ̀ Microsoft náà Àpèjúwe ti Service Pack 3 fún Office Language Interface Pack 2007 (KB2526307) fún ìwífún síwájú nípa ìṣàfikún yí.

  Awọn Gbaa Lati Ayelujara to Gbajumọ

  Loading your results, please wait...

  Awọn ìmúdójúìwọ̀n PC ọ̀fẹ́

  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n aṣàtúnṣe sí àbò
  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n ẹ̀yà àìrídìmú
  • Awọn àkójọpọ̀ iṣẹ́
  • Awọn awakọ̀ ẹ̀yà àfojúrí