Internet Explorer

Internet Explorer 9 ti Windows fun Windows 7

Yi Ede Pada:
Internet Explorer 9 ti Windows ń jẹ́ki àwọn oju-opo wẹ́ẹ̀bù rẹ tàn ki wọ́n sì ṣiṣẹ́ bíi àwọn àtòjọ-eto tiwa-n-tiwa lori PC rẹ.
 • Awọn àlàyé

  Ẹya:
  Ọjọ Igbejade:

  9.0.7930.16406

  22/6/1432

  Orukọ Faili:
  Iwọn Faili:

  IE9-Windows7-x86-yor.exe

  17.8 MB

  Orisun Imọ (KB) Awọn Agbelẹkọ: KB982861
   Windows Internet Explorer 9 n fi àwọn oju-opo wẹ́ẹ̀bù ati àwọn àtòjọ-eto tó farajọ tó si ń ṣiṣẹ́ bíi àwọn àtòjọ-eto PC tiwa-n-tiwa nipaṣẹ̀ agbara ti Windows jíṣẹ́ funni
   • Yíyára: Internet Explorer 9 jẹ́ eyiti o fi gbogbo ara yára. Ti a ṣàgbékalẹ̀ lati ṣamulo anfani ti ẹ̀yà aridimu líle PC rẹ nipaṣẹ̀ Windows, Internet Explorer 9 ń fi àwọn ìrírí alaworan afihan tó kun fọ́fọ́ ti o yára tí o si ń danilohun bíi àwọn àtòjọ-eto tiwa-n-tiwa lori PC rẹ jíṣẹ́.
   • Ìmọ́tótó: Internet Explorer n gbájúmọ́ orí àwọn oju-opo Wẹ́ẹ̀bù ti o fẹ́ràn pẹ̀lú ìwò tó mọ́ tótó ati agbegbe ìwò to ga síi eyiti o n mu àwọn oju-opo Wẹ́ẹ̀bù to n tàn gbinrin. Àgbékalẹ̀ ti èrò inu ti kò wọ́ rárá pẹ̀lú Windows 7 ń pese iraye si ìsíra tẹ̀ kan si àwọn àtòjọ-eto Wẹ́ẹ̀bù ti a somọ́ tààrà si Pẹpẹ-iṣẹ́.
   • Tó Ṣeé Gbẹ́kẹ̀lé: Internet Explorer jẹ ọ̀nà tó ṣeé gbẹ́kẹ̀lé kan si Wẹ́ẹ̀bù nitoripe o ni akojopọ̀ ààbò agbesinu kan tó gbópọn, ìpamọ́ ati àwọn ìmọ̀-ẹ̀rọ ìṣeégbẹ́kẹ̀lé ti o ń mu ọ wà ninu aabo síi ti o sì ń jẹ́kí ìrírí ìṣàwákiri rẹ jẹ́ ailanidaduro.
   • Tí o Ṣeé lò Ninu Ọ̀pọ̀ Ẹ̀rọ: Àtìlẹyìn fun HTML5 ati àwọn gbedeke Wẹ́ẹ̀bù igbalode ti a ṣagbelẹrọ lati ṣamulo anfani ti GPU ń tumọ̀̀̀ sì pe kì í ṣe wipe iye ayipada kan náà ń ṣiṣẹ́ kaakiri Wẹ́ẹ̀bù nikan, ṣùgbọ́n o ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lu ìyára síi atipe o funni ni iriri tó kun fọ́fọ́ nipaṣẹ̀ Windows ati Internet Explorer 9.
 • Awọn Ohun ti Ẹrọ nilo lati Sişẹ

  Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:

  Windows 7

    • Windows 7
    • Windows 7 pẹ̀lú Service Pack 1
   • Kọ̀ǹpútà/ Olùgbéṣẹ́ṣe: Kọ̀ǹpútà pẹlú ̀olùgbéṣẹ́ṣe 233MHz tabi jù bẹ́ẹ̀ lọ (Olùgbéṣẹ́ṣe Pentium ni a gbani niyanju rẹ̀)
   • Ìrántí: 512MB
   • Ààyè Dísìkì Aridimu Líle:70MB
   • Àfihàn: Super VGA (800 x 600) ti amaworantan oníìtẹjúmọ́ àwọ̀ to ga pẹ̀lú àwọn àwọ 256.
   • Àwọn Àsomọ́ra: Modẹ́ẹ̀mù tabi ìsopọ̀ Íntánẹ́ẹ̀tì; Atọ́ka Microsoft, Atọ́kaỌlọ́pọlọ Microsoft, tabi ohun-èlò atọ́ka tó báramu.
 • Awọn Ilana

   1. Síra tẹ bọ́tìnnì Gba Ẹ̀dà Faili Sọ̀kalẹ̀ loju iwe yìí lati bẹ̀rẹ̀ gbigba ẹ̀dá faili náà sọ̀kalẹ̀.
   2. Ṣe ọ̀kan ninu àwọn àtẹ̀lé wọ̀nyí:
    • Lati bẹ̀rẹ̀ ìṣagbekalẹ̀ naa loju-ẹṣẹ́, síra tẹ Ṣíi or Fi àtòjọ-eto yii ṣiṣẹ́ lati ibi tó wà lọ́wọ́lọ́wọ́.
    • Lati ṣẹ̀dà faili ti a gbà sí ori kọ̀ǹpútà rẹ fun iṣagbekalẹ̀ ni igba miran, síra tẹ Ṣafipamọ́ tabi Ṣafipamọ́ àtòjọ-eto yìí si dísìkì.
 • Afinku Alaye

 • Awọn ohun amuşọrọ ti o jọ eyi

Awọn Gbaa Lati Ayelujara to Gbajumọ

Awọn ìmúdójúìwọ̀n PC ọ̀fẹ́

 • Awọn ìmúdójúìwọ̀n aṣàtúnṣe sí àbò
 • Awọn ìmúdójúìwọ̀n ẹ̀yà àìrídìmú
 • Awọn àkójọpọ̀ iṣẹ́
 • Awọn awakọ̀ ẹ̀yà àfojúrí
Tan Ìmúdójìwọ̀n Microsoft
paádé
moreinfo