Office

  Àwọn Irinṣẹ́ Wíwádìí Microsoft Office 2013 - Yorùbá

  Yi Ede Pada:
  Microsoft Office Proofing Tools ń gba ìṣàtúnṣe láàyè ní àwọn èdè àfikún.
  • Note:There are multiple files available for this download.Once you click on the "Download" button, you will be prompted to select the files you need.
   Ẹya:

   2013

   Orukọ Faili:

   proofingtools_yo-ng-x86.exe

   proofingtools_yo-ng-x64.exe

   Ọjọ Igbejade:

   25/2/1434

   Iwọn Faili:

   853 KB

   903 KB

    Ṣé o fẹ́ ṣàyẹ̀wò ọ̀rọ̀ ìkọsílẹ̀ fún èdè kan tí Office kò ṣàgbékalẹ̀ bí? O wà ní ibi tí ó tọ̀nà. Microsoft Office Proofing Tools pẹ̀lú ètò kíkún ti àwọn irinṣẹ́ wíwádìí tó wà fún Office ní èdè yìí. Ṣàá ti ṣàgbékalẹ̀ kí o sì ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ Office, àti àwọn irinṣẹ́ wíwádìí nítorípé èdè rẹ ti ṣetán láti lọ.
  • Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:

   Windows 7, Windows 8, Windows Server 2008 R2

    Ìgbàsílẹ̀ yìí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn àtòjọ-ètò wọ̀nyí:
    Microsoft Office Excel 2013
    Microsoft Office OneNote 2013
    Microsoft Office Outlook 2013
    Microsoft Office PowerPoint 2013
    Microsoft Office Word 2013
   • Láti ṣàgbékalẹ̀ ìgbàsílẹ̀ yìí:
    Ṣàgbékalẹ̀ àwọn irinṣẹ́ ìwádìí:


    1. Gbà fáìlì náà sílẹ̀ nípa títẹ Bọ́tìnnì ìgbàsílẹ̀ (lókè) kí o sì fi fáìlì náà pamọ́ sínú àwo gbagidi rẹ.
    2. Mú àtòjọ-ètò ìṣètò náà ṣiṣẹ́.
    3. Lójú-ìwé Ka Àwọn Àdéhùn Àṣẹ Ẹ̀yà Àìrídìmú ti Microsoft, ṣàgbéyẹ̀wò àwọn àdéhùn, yan "Tẹ ibí láti faramọ́ Àwọn Àdéhùn Àṣẹ Ẹ̀yà Àìrídìmú ti Microsoft" àpótí àyẹ̀wò, lẹ́yìn náà tẹ Tẹ̀síwájú.
    4. Àmọ̀ràn ìṣètò ń ṣiṣẹ́ ó sì ń ṣàgbékalẹ̀ àwọn irinṣẹ́ ìwádìí.
    5. Lẹ́yin tí àgbékalẹ̀ náà bá ti parí, ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ àwọn ìfilọ́lẹ̀ ṣí Office.


    Àwọn ìtọ́ni fún lílò: Ṣáà ti lo àwọn irisẹ́ wíwádìí bí o ti máa ń ṣe - o gbọ́dọ̀ rí wọn báyìí fún èdè tuntun tí o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣàgbékalẹ̀. Fún àpẹrẹ, o le ṣètò èdè wíwádìí rẹ sí èdè tuntun láti lo àyẹ̀wò ọ̀rọ̀ ìkọsílẹ̀ (tí ó bá wà) - láti kọ́ bí a ti ń ṣe èyí, wo Yí láàrín àwọn oríṣì;i èdè nípa ṣíṣètò èdè wíwádìí

    Láti yọ ìgbàsílẹ̀ yì;i kúrò:
    1. Lórí mẹ́nù Bẹ̀rẹ̀, the Start menu, tọ́ka sí Ètò lẹ́yìn náà tẹ Pánẹ̀lì Ìdarí.
    2. Tẹ-lẹ́ẹ̀mejì Àwọn Àtòjọ-ètò Ṣàfikún/Yọkúrò.
    3. Nínú àkójọ àwọn àtòjọ-ètò tí a ṣàgbékalẹ̀ láìpẹ́, yan Àwọn Irinṣẹ́ Wíwádìí Microsoft Office 2013 - [Yorùbá] lẹ́yìn náà tẹ Ṣe àìgbékalẹ̀, Yọkúrò, tàbí Ṣàfikún/Yọkúrò. Tí àpótí ìsọ̀rọ̀gbèsì bá farahàn, tẹ́lé àwọn ìtọ́ni láti yọ àtòjọ-ètò kúrò.
    4. Tẹ Bẹ́ẹ̀ni tàbí Ó DÁRA láti ṣàrídájú pé o fẹ́ yọ àtòjọ-ètò náà kúrò.


  Awọn Gbaa Lati Ayelujara to Gbajumọ

  Loading your results, please wait...

  Awọn ìmúdójúìwọ̀n PC ọ̀fẹ́

  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n aṣàtúnṣe sí àbò
  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n ẹ̀yà àìrídìmú
  • Awọn àkójọpọ̀ iṣẹ́
  • Awọn awakọ̀ ẹ̀yà àfojúrí