Microsoft Office Proofing Tools ń gba ìṣàtúnṣe láàyè ní àwọn èdè àfikún.
Note:There are multiple files available for this download.Once you click on the "Download" button, you will be prompted to select the files you need.
proofingtools_yo-ng-x86.exe
proofingtools_yo-ng-x64.exe
Ṣé o fẹ́ ṣàyẹ̀wò ọ̀rọ̀ ìkọsílẹ̀ fún èdè kan tí Office kò ṣàgbékalẹ̀ bí? O wà ní ibi tí ó tọ̀nà. Microsoft Office Proofing Tools pẹ̀lú ètò kíkún ti àwọn irinṣẹ́ wíwádìí tó wà fún Office ní èdè yìí. Ṣàá ti ṣàgbékalẹ̀ kí o sì ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ Office, àti àwọn irinṣẹ́ wíwádìí nítorípé èdè rẹ ti ṣetán láti lọ.
Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:
Windows 7; Windows 8; Windows Server 2008 R2
Ìgbàsílẹ̀ yìí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn àtòjọ-ètò wọ̀nyí:
Microsoft Office Excel 2013
Microsoft Office OneNote 2013
Microsoft Office Outlook 2013
Microsoft Office PowerPoint 2013
Microsoft Office Word 2013
Láti ṣàgbékalẹ̀ ìgbàsílẹ̀ yìí:
Ṣàgbékalẹ̀ àwọn irinṣẹ́ ìwádìí:
- Gbà fáìlì náà sílẹ̀ nípa títẹ Bọ́tìnnì ìgbàsílẹ̀ (lókè) kí o sì fi fáìlì náà pamọ́ sínú àwo gbagidi rẹ.
- Mú àtòjọ-ètò ìṣètò náà ṣiṣẹ́.
- Lójú-ìwé Ka Àwọn Àdéhùn Àṣẹ Ẹ̀yà Àìrídìmú ti Microsoft, ṣàgbéyẹ̀wò àwọn àdéhùn, yan "Tẹ ibí láti faramọ́ Àwọn Àdéhùn Àṣẹ Ẹ̀yà Àìrídìmú ti Microsoft" àpótí àyẹ̀wò, lẹ́yìn náà tẹ Tẹ̀síwájú.
- Àmọ̀ràn ìṣètò ń ṣiṣẹ́ ó sì ń ṣàgbékalẹ̀ àwọn irinṣẹ́ ìwádìí.
- Lẹ́yin tí àgbékalẹ̀ náà bá ti parí, ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ àwọn ìfilọ́lẹ̀ ṣí Office.
Àwọn ìtọ́ni fún lílò: Ṣáà ti lo àwọn irisẹ́ wíwádìí bí o ti máa ń ṣe - o gbọ́dọ̀ rí wọn báyìí fún èdè tuntun tí o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣàgbékalẹ̀. Fún àpẹrẹ, o le ṣètò èdè wíwádìí rẹ sí èdè tuntun láti lo àyẹ̀wò ọ̀rọ̀ ìkọsílẹ̀ (tí ó bá wà) - láti kọ́ bí a ti ń ṣe èyí, wo Yí láàrín àwọn oríṣì;i èdè nípa ṣíṣètò èdè wíwádìí
Láti yọ ìgbàsílẹ̀ yì;i kúrò:
- Lórí mẹ́nù Bẹ̀rẹ̀, the Start menu, tọ́ka sí Ètò lẹ́yìn náà tẹ Pánẹ̀lì Ìdarí.
- Tẹ-lẹ́ẹ̀mejì Àwọn Àtòjọ-ètò Ṣàfikún/Yọkúrò.
- Nínú àkójọ àwọn àtòjọ-ètò tí a ṣàgbékalẹ̀ láìpẹ́, yan Àwọn Irinṣẹ́ Wíwádìí Microsoft Office 2013 - [Yorùbá] lẹ́yìn náà tẹ Ṣe àìgbékalẹ̀, Yọkúrò, tàbí Ṣàfikún/Yọkúrò. Tí àpótí ìsọ̀rọ̀gbèsì bá farahàn, tẹ́lé àwọn ìtọ́ni láti yọ àtòjọ-ètò kúrò.
- Tẹ Bẹ́ẹ̀ni tàbí Ó DÁRA láti ṣàrídájú pé o fẹ́ yọ àtòjọ-ètò náà kúrò.