Àkópọ̀ Èdè Òjísẹ́ (LIP) Windows 8 ń pèsè ẹ̀yà tí a ṣọ̀tumọ̀ rẹ̀ díẹ̀ ní àwọn àgbègbè tí a ti lo Windows 8.
Note:There are multiple files available for this download.Once you click on the "Download" button, you will be prompted to select the files you need.
LIP_yo-NG-32bit.mlc
LIP_yo-NG-64bit.mlc
Àkópọ̀ Èdè Òjísẹ́ (LIP) Windows ń pèsè ẹ̀yà tí a ṣọ̀tumọ̀ rẹ̀ díẹ̀ ní àwọn àgbègbè tí a ti lo Windows. Lẹ́yìn tí a ti fisípò tán LIP, àyọkà nínú àwọn onímọ̀, àwọn àpótí àjọsọ, àwọn mẹ́nù, àti àwọn àkọlé Ìrànwọ́ àti Àtìlẹ́yìn ní a máa ṣàfihàn nínú èdè LIP. Àyọkà tí a kò bá túmọ̀ máa wá nínú èdè ìṣàlẹ̀ Windows 8. Fún àpẹrẹ, tí o bá ti ra ẹ̀yà Spanish Windows 8, tí o si fi Catalan LIP sípò, àwọn àyọkà kan máa wà ní Spanish. O le fi jù LIP kan sípò lórí èdè ìsàlẹ̀ kan lọ. A le fi àwọn LIP Windows sípò lórí gbogbo àwọn ẹ̀yà Windows 8.
Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:
Windows 8
- Fún Àmúlò Ẹ̀rọ, ṣíra tẹ̀ níbí
- Fún àwọn Ìtọ́ni Àkọ́-Físípò, ṣíra tẹ̀ níbí
- Ṣíra tẹ bọ́tìnì Gbàsílẹ̀ lórí ojú ìwé láti bẹ̀rẹ̀ gbígbàsílẹ̀, tàbí yan èdè míràn láti àtòjọ jábọ́-sílẹ̀.
- Ṣe ọ̀kan nínú ìwọ̀nyí:
- Láti bẹ̀rẹ̀ ìfisípò ní kíá, ṣíra tẹ Sí.
- Láti ṣàfipamọ́ àgbàsílẹ̀ sí kọ̀ńpútà rẹ fún ìfisípò ní gbà tó báyá, ṣíra tẹ Ṣàfipamọ́
- Fún Lẹ́yìn àwọn Ìtọ́ni Àkọ́-Físípò, ṣíra tẹ̀ níbí
- Fún àwọn Ìsòro Tí a mọ̀, ṣíra tẹ̀ níbí