Internet Explorer

  Internet Explorer 10 fún àwọn Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nínú IT àti àwọn Olùmúgbèrú fún Windows 7

  Yi Ede Pada:
  Internet Explorer 10 ń jẹ́ kí àwọn àyè lórí ayélujára rẹ ṣe gẹ́lẹ́ bíi àwọn ìfilọ́lẹ̀ abẹ́lé lórí PC rẹ.
  • Ẹya:

   10.0.9200.16521

   Orukọ Faili:

   IE10-Windows6.1-x86-yo-ng.exe

   Ọjọ Igbejade:

   15/4/1434

   Iwọn Faili:

   22.5 MB

   Orisun Imọ (KB) Awọn Agbelẹkọ: KB2718695

    Internet Explorer 10. Yára ó sì ńsáré fún Windows 7.
  • Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:

   Windows 7 Service Pack 1

    • Kọ̀ǹpútà/ Odó ìṣirò kọ̀ǹpútà Kọ̀ǹpútà pẹ̀lú odó ìṣirò kọ̀ǹpútà 233MHz tàbí ju bẹ́ẹ̀ lọ (Odó ìṣirò kọ̀ǹpútà pẹ́ntíọ̀mù ni a gbàníyànjú)
    • Àpò ìrántí: 512MB
    • Àyè Àwo àká-ọ̀rọ̀ Gbagidi:70MB
    • Àfihàn: VGA gidi (800 x 600) tàbí aṣàfihàn ìtànsán-gíga pẹ̀lú àwọn àwọ̀ 256.
    • Àwọn ẹ̀yà ara: Módẹ̀mù tàbí Ìsopọ̀ ayélujára; Atọ́ka Microsoft, Microsoft IntelliMouse, tàbí ẹ̀rọ ìtọ́ka tó dọ́gba.
    1. Tẹ Ìgbàsílẹ̀ bọ́tìnnì lórí ojú-ìwé yìí láti bẹ̀rẹ̀ ìgbàsílẹ̀ náà.
    2. Ṣe ọ̀kan nínú ìwọ̀nyí:
     • Láti bẹ̀rẹ̀ àgbékalẹ̀ lójú ẹsẹ̀, tẹ Ṣí tàbí Mú ètò yìí ṣiṣẹ́ láti ipò rẹ ìsinsìnyí
     • Láti da ìgbàsílẹ̀ kọ sórí kọ̀ǹpútà rẹ fún àgbékalẹ̀ lọ́jọ́ iwájú, tẹ Ṣàfipamọ́ tàbí Ṣàfipamọ́ ètò yìí sí dísíkì

  Awọn Gbaa Lati Ayelujara to Gbajumọ

  Loading your results, please wait...

  Awọn ìmúdójúìwọ̀n PC ọ̀fẹ́

  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n aṣàtúnṣe sí àbò
  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n ẹ̀yà àìrídìmú
  • Awọn àkójọpọ̀ iṣẹ́
  • Awọn awakọ̀ ẹ̀yà àfojúrí