Internet Explorer

  Internet Explorer 11 (64-Bit)

  Yi Ede Pada:
  Internet Explorer 11 a má a mú ayélujára tàn bíi iná lórí Windows 7. Nísìyí pẹ̀lú Bing àti MSN bí ipò àìyípadà.
  • Ẹya:

   11.0.0.1

   Orukọ Faili:

   EIE11_YO-NG_MCM_WIN764.EXE

   Ọjọ Igbejade:

   8/8/1435

   Iwọn Faili:

   56.8 MB

    Yíyára síi. Ààbò síwájú síi. Internet Explorer 11 a má a mú ayélujára tàn bíi iná lórí Windows 7. Nísìyí pẹ̀lú Bing àti MSN bí ipò àìyípadà fún ìrírí ayélujára tí ó ti tẹ̀síwájú
    • Yíyára: Yíyára ní kíkó àwọn ààyè jọ pọ̀, a sì má a lọ déédé bí o tí nlọ káàkiri wọn.
    • Ìrọ̀rùn: Ìrọ̀rùn pẹ̀lú Windows, a kàn má a ṣiṣẹ́ bí o ti fẹ́ ẹ.
    • Ààbò síwájú síi: Ààbò tó dára síi lọ́wọ́ àwọn ohun èlò búrburú aṣejàmbá àti àṣírí bíbò síwájú síi lórí ayélujára.
    • Ojú-ìwé àkọ́kàn: Mọ ohun tí nlọ pẹ̀lú ìròyìn titun jùlọ, eré ìje, àti ìdánilárayá pẹ̀lú MSN bíi ojú-ìwé àkọ́kàn rẹ.
    • Wá nkan kiri pẹ̀lú & gba ẹ̀bùn: Nísìyí gba ẹ̀bùn pẹ̀lú àwọn káàdì ẹ̀bùn àti àwọn ohun mìíràn fún wíwá nkan kiri pẹ̀lú Bing láti ojú-ìwé àkọ́kàn MSN rẹ.

    Àyélujára tí a ronú lọ́nà mìíràn
    Ṣàwárí àwọn ààyè ayélujára titun tí a gbékalẹ̀ pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Internet Explorer. Láti àwọn òkè gegele Everest títí dé ayé ìyanilẹ́nu Contre Jour, ní ìrírí ẹwà ayélujára nínú Internet Explorer.
    Wo àwọn ààyè náà

    Máṣe pàdánù
    Fí Internet Explorer ṣe ẹ̀rọ aṣàwákiri àìyípadà rẹ. Lọ kiri ayélujára pẹ̀lú ẹ̀rọ aṣàwákiri yíyára, rírọrùn, pípé-láti-fọwọ́kàn.
    Mọ̀ bí a ti nṣe é
  • Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:

   Windows 7 Service Pack 1

    • Kọmputa/ Aṣètò ìgbésẹ̀: Kọmputa pẹ̀lú aṣètò ìgbésẹ̀ 233MHz tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ (A dámọ̀ràn aṣètò ìgbésẹ̀ Pentium)
    • Ààyè ìrántí: 512MB
    • Ààyè Awakọ̀ Ẹ̀yà Àfojúrí ti inú:70MB
    • Àfihàn: Super VGA (800 x 600) tàbí alabojuto rẹsoluṣọn tó ga pẹ̀lú àwọn àwọ̀ 256.
    • Àwọn ẹ̀yà tó ṣeé yọ kúrò: Módẹ̀mù tàbí àsopọ̀ Ayélujára; Máùsì Microsoft, Microsoft IntelliMouse, tàbí ẹ̀rọ àtọ́ka mìíràn tó báamu.
   • Láti fi Internet Explorer 11 sórí ẹ̀rọ, tẹ Gbàá láti ayélujára, kí o sì tẹ̀lé àwọn ìtọ́sọ́nà tí ó wà lórí ìbòjú rẹ̀.

  Awọn Gbaa Lati Ayelujara to Gbajumọ

  Loading your results, please wait...

  Awọn ìmúdójúìwọ̀n PC ọ̀fẹ́

  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n aṣàtúnṣe sí àbò
  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n ẹ̀yà àìrídìmú
  • Awọn àkójọpọ̀ iṣẹ́
  • Awọn awakọ̀ ẹ̀yà àfojúrí