Windows

  Windows Vista Language Interface Pack

  Yi Ede Pada:
  Windows Vista Language Interface Pack (LIP) ń pèsè Òjíṣẹ́ Asàmúlò tí a túmọ̀ ní èdè ìbílẹ̀ tí àwọn agbègbè Windows Vista tí a túmọ̀ tí a ń lò dáradára
  • Ẹya:

   1.0

   Orukọ Faili:

   LIP_yo-NG.mlc

   Ọjọ Igbejade:

   27/5/1430

   Iwọn Faili:

   2.6 MB

    Windows Vista Language Interface Pack (LIP) ń pèsè ọ̀nà ìgbọ́rọ̀sí tí àwọn agbègbè Windows Vista tí a túmọ̀ tí a ń lò dáradára. Lẹ́yìn tí a bá fi LIP sórí ẹ̀rọ tán, ọ̀rọ̀ nínú àwọn onímọ̀, àwọn àpótí ìjíròrò, àwọn ìwé ètò, àwọn àkòrí Ìrànwọ́ àti Àtìlẹ́yìn, àti àwọn ohun míràn nínú òjíṣẹ́ asàmúlò ní a má ṣàfihàn nínú èdè LIP. Ọ̀rọ̀ tí a kò túmọ̀ má wà ní ìsàlẹ̀ èdè Windows Vista. Fún àpẹrẹ, tí o bá ra ọ̀nà ìgbọ́rọ̀sí Windows Vista ará Ṣípánísì, tí o sì fi LIP Kàtálánì sórí ẹ̀rọ, àwọn ọ̀rọ̀ má wà ní èdè Ṣípánísì. O le fi ju LIP kan sórí ẹ̀rọ, fún ìdí èyí asàmúlò kọ̀mpútà kọ̀kan le ṣàfihàn òjísẹ́ asàmúlò ní èdè tí wọ́n fẹ́.
  • Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:

   Windows Vista

    • Microsoft Windows Vista
    • Òjísẹ́ asàmúlò inú èdè (àwọn) wọ̀nyí: Gẹ̀ẹ́sì
    • 4.63 Mb àlàfo tósófo láti gbàsílẹ̀
    • 15 Mb àlàfo tósófo láti sàgbẹkalẹ̀

    Àwọn Pẹpẹ tí a faramọ́: LIPs le ṣisẹ́ pẹ̀lú àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀sí 32-bit ti Windows Vista kò sì le ṣé fi sórí àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀sí Windows tàbí sórí àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀sí 64-bit ti Windows Vista.
    1. Tẹ bọ́tìnì Gbàsílẹ̀ lórí ojú ìwé yìí láti bẹ̀rẹ̀ ìgbàsílẹ̀, tàbí yan èdè míràn láti àkọsílẹ̀ jábọ́-sílẹ̀ kí o sì tẹ Lọ.
    2. Ṣé ọ̀kan nínú àwọn wọ̀nyí:
     • Láti bẹ̀rẹ̀ ìfisórí ẹ̀rọ ní kíákíá, tẹṢí tàbí Ṣí ètò yìí áti ibùgbé lọ́wọ́lọ́wọ́.
     • Láti ṣẹ̀dà ìgbàsílẹ̀ sí kọ̀mpútà rẹ fún ìfisórí ẹ̀rọ nígbà tóbáyá, tẹ Ṣàfipamọ́ tàbí Ṣàfipamọ́ ètò yìí sí dísìkì.

  Awọn Gbaa Lati Ayelujara to Gbajumọ

  Loading your results, please wait...

  Awọn ìmúdójúìwọ̀n PC ọ̀fẹ́

  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n aṣàtúnṣe sí àbò
  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n ẹ̀yà àìrídìmú
  • Awọn àkójọpọ̀ iṣẹ́
  • Awọn awakọ̀ ẹ̀yà àfojúrí