Office

  Microsoft Office Language Interface Pack 2010 – Yoruba

  Yi Ede Pada:
  Microsoft Office Language Interface Pack 2010 – Yoruba máa pèsè òjíṣẹ́ aṣàmúlò Yoruba fún ọ̀pọ̀ ètò Microsoft Office 2010.
  • Note:There are multiple files available for this download.Once you click on the "Download" button, you will be prompted to select the files you need.
   Ẹya:

   1

   Orukọ Faili:

   languageinterfacepack-x86-yo-ng.exe

   languageinterfacepack-x64-yo-ng.exe

   O14LipHelp-yo-ng.chm

   Ọjọ Igbejade:

   17/8/1432

   Iwọn Faili:

   13.4 MB

   15.0 MB

   212 KB

    Microsoft Office Language Interface Pack 2010– Yoruba máa ń pèsè Yoruba òjíṣẹ́ aṣàmúlò fún:
    • Microsoft Office Excel 2010

    • Microsoft Office OneNote 2010

    • Microsoft Office Outlook 2010

    • Microsoft Office PowerPoint 2010

    • Microsoft Office Word 2010
  • Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:

   Windows 7, Windows Vista Service Pack 2

    • A nílò ẹ̀yá àìrídìmú: Èyíkéyìí ẹ̀dà àkójọ tàbí àdádúró Microsoft Office 2010 tí ó ní ọ̀kan tàbí ọ̀pọ̀ àtòjọ̀-ètò: Excel, OneNote, Outlook, PowerPoint tàbí Word.
    • Ààyè dísìkì tí a nílò: Ní àfikún sí ààyè àwo tí àwọn ètò Office 2010 tí a fi sípò lọ́wọ́lọ́wọ́ ńlò, 20 mẹ́gàbàtì (MB) ààyè àwo tó wà lárọ̀wọ́tọ́ ni a nílò.
   • Láti ṣe ìfisípò àgbàsílẹ̀ yìí:
    1. Ṣe àgbàsílẹ LanguageInterfacePack.exe fáìlì nípa titẹ Àgbàsílẹ̀ bọ́tìnì (lápá òkè) kí o wá ṣètọ́jú fáìlì náà sí àwo gbagidi rẹ.
    2. Ṣíra tẹ̀ẹ́ lẹ́ẹ̀mejì LanguageInterfacePack.exe Ètò fáìlì lórí àwo gbagidi rẹ láti bẹ̀rẹ̀ Àgbékalẹ̀ ètò.
    3. Tẹ̀lé àwọn ìlànà lórí aṣàfihàn láti ṣèparí ìfisípò náà.
    4. Lẹ́yìn tí o bá ti ṣe ìfisípò, o le rí fáìlì kà-mí fún Àkópọ̀ èdè Òjíṣẹ́ Microsoft Office 2010 ní C:\Program Files\Common Files\microsoft shared\OFFICE14\LCID\LIPread.htm
    5. Kò sí àtìlẹyìn ṣíṣàfikún Office 2007 pẹ̀lú Àkópọ̀ Òjíṣẹ́ Èdè Office 2007 tàbí ẹ̀yà ìsaájú sí Office 2010 pẹ̀lú Àkópọ̀ Òjíṣẹ́ Èdè Office 2010. Tí o bá wù ọ́ láti ṣàfikún ìpìlẹ̀ ìfisípò Office 2007 sí Office 2010 pẹ̀lú Àkópọ̀ Òjíṣẹ́ Èdè 2010 o le:
     • Ṣíṣàyọkúrò Office 2007 Language Interface Pack
     • Mú àgbékalẹ̀ Office 2010 ṣiṣẹ́ kí o wá ṣàfikún ẹ̀yàn.
     • Nígbà tí àgbékalẹ̀ Office 2010 bá ti parí, ṣe ìfisípò àti àtòpọ̀ Office 2010 Language Interface Pack


     • Ń sọ àgbéjáde Office rẹ di aṣiṣẹ́:
     • Tí o bá ní ìṣòro nípa kíka gbogbo Kóòdù ìfisípò lórí ìjíròrò "Microsoft Office Activation Wizard" , tàbí kí gbogbo kóòdù ìfisípò má farahàn bí ó ṣe yẹ nígbàtí o bá ń lo Microsoft® Office Language Interface Pack 2010, jọ̀wọ́ ṣèparẹ́ onímọ̀ kí o ṣípòpadà sí àgbéjáde English US láti ṣe ìsọjí Àgbéjáde Microsoft Office.


    Ìtọ́sọ́nà fún lìlò:

    Látí ṣe ìpapòdà òjíṣẹ́ aṣàmúlò sí èdè Microsoft Office Language Interface Pack 2010– Yoruba, Tẹ̀lé àwọn ìgbéṣẹ̀ wọ̀nyìí:

    1. Bẹ̀rẹ̀ Àwọn ohun ìnífẹ̀síí Èdè Microsoft Office 2010 Láti Bẹ̀rẹ̀\Gbogbo Ètò\Microsoft Office\Àwọn irinṣẹ́ Microsoft Office mẹ́nù.
    2. Lábẹ́ Yan Aṣàfihàn àti Àwọn Èdè Ìrànwọ́, lábẹ́ Ṣàfihàn Èdè yan èdè tí a nílò kí o wá tẹ orí i Ṣàgbékalẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i Àkùnàyàn bọ́tìnnì.
    3. Lábẹ́ Yan Àwọn Èdè Ìṣàtúnṣe, yan èdè tí o nílò kí o tẹ Ṣàgbékalẹ̀ gẹ́gẹ́bí Àkùnàyàn bọ́tìnnì.
    4. tẹ Ó DA bọ́tìnnì.

    Àwọn ààtò èdè tí a ti yàn máa bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ nígbàmíràn tí o bá tún bẹ̀rẹ̀ Office rẹ.
    Àkíyèsí: Ìrànwọ́ kò ṣeé ṣí nípò padà sí èdè Microsoft Office Language Interface Pack 2010– Yoruba. Ìranwọ́ máa má wà ní èdè ìfisípò titẹ́lẹ̀.
    Máa sábà ṣàgbékalẹ̀ ìfihàn ìrànwọ́ nínú àtòkọ àṣẹ́yọsílẹ̀ sí English US.

    Láti ṣàyọkurò àgbàsílẹ̀ yìí:
     Tẹ̀lé àwọn ìgbéṣẹ̀ wọ̀nyìí lórí ẹ̀yà Windows XP Home tàbí Professional:
    1. Jáde nínu gbogbo ètò.
    2. Ṣíra tẹ̀ẹ́ lẹ́ẹ̀mejì Ṣàfikún tàbí ṣàyọkúrò àwọn ètò àwòrán aṣàmì ní Pánẹ̀ẹ̀lì Ìdarí Windows.
    3. Tẹ̀ Microsoft Office Language Interface Pack 2010 Nínú u Àwọn ètò tí a fisípò lọ́wọ́lọ́wọ̀ àpótí, lẹ́hìn náà tẹ Ṣàyọkúrò bọ́tìnnì.
    4. Tẹ̀lé ìlànà lojú aṣàfihàn.

     Tẹ̀lé àwọn Ìgbéṣẹ̀ wọ̀nyí lórí Windows Vista tàbí Windows 7:
    1. Jáde nínu gbogbo ètò.
    2. Ṣíra tẹ̀ẹ́ lẹ́ẹ̀mejì Àwọn Ètò àti Àdámọ́ àwòrán aṣàmì ní Windows Pánẹ̀ẹ̀lì Ìdarí.
    3. Nínú u Ṣàgbékúrò tàbí Ṣàyípadà Ètò Kan Ẹ̀yàn, tẹ Microsoft Office Language Interface Pack 2010– Yoruba Nínú u Àwọn Ètò tí a tí ṣe ìfisípò wọn lọ́wọ́lọ́wa àpótí, lẹ́hìn náà yàn Ṣàgbékúrò ẹ̀yàn.
    4. Tẹ̀lé ìlànà lojú aṣàfihàn.    Ti o ko ba le wo àwọn ohun inú faili CHM lẹhin igbàsílẹ` rẹ, o le ṣe awọn igbesẹ wọnyi eyiti yoo fun ọ ni anfani lati wo àwọn ohun inú naa :
    1. Ṣii fódà ibiti o ti ṣe gbàsílẹ faili CHM naa.
    2. Tẹ lori CHM lẹẹméjì lati inu mẹnù tíó farahàn, yan Àwọn ohun ìní.
    3. Ni Táábù gbogboògbò, tẹ Bọtìnì àìdí lẹhinna tẹ bọtìnì Ó DA.
    4. Tẹ lori faili CHM lẹẹméjì ni bayi iwọ yoo ni anfani lati rii àwọn ohun inú rẹ.

  Awọn Gbaa Lati Ayelujara to Gbajumọ

  Loading your results, please wait...

  Awọn ìmúdójúìwọ̀n PC ọ̀fẹ́

  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n aṣàtúnṣe sí àbò
  • Awọn ìmúdójúìwọ̀n ẹ̀yà àìrídìmú
  • Awọn àkójọpọ̀ iṣẹ́
  • Awọn awakọ̀ ẹ̀yà àfojúrí