Yára síi. Ààbò síwájú síi. Internet Explorer 11 ni ẹ̀rọ aṣàwákiri tí a dámọ̀ràn fún Windows 7.
IE11-Windows6.1-x64-yo-ng.exe
Yára síi. Ààbò síwájú síi. Internet Explorer 11 ni ẹ̀rọ aṣàwákiri tí a dámọ̀ràn fún Windows 7.
Awọn Ohun Elo Isẹ-sişe ti a Gbarukuti:
Windows 7 Service Pack 1; Windows Server 2008 R2 SP1
- Kọ̀ǹpútà/ Odó ìṣirò kọ̀ǹpútà Kọ̀ǹpútà pẹ̀lú odó ìṣirò kọ̀ǹpútà 233MHz tàbí ju bẹ́ẹ̀ lọ (Odó ìṣirò kọ̀ǹpútà pẹ́ntíọ̀mù ni a gbàníyànjú)
- Àpò ìrántí: 512MB
- Àyè Àwo àká-ọ̀rọ̀ Gbagidi:70MB
- Àfihàn: VGA gidi (800 x 600) tàbí aṣàfihàn ìtànsán-gíga pẹ̀lú àwọn àwọ̀ 256.
- Àwọn ẹ̀yà ara: Módẹ̀mù tàbí Ìsopọ̀ ayélujára; Atọ́ka Microsoft, Microsoft IntelliMouse, tàbí ẹ̀rọ ìtọ́ka tó dọ́gba.
- Tẹ Ìgbàsílẹ̀ bọ́tìnnì lórí ojú-ìwé yìí láti bẹ̀rẹ̀ ìgbàsílẹ̀ náà.
- Ṣe ọ̀kan nínú ìwọ̀nyí:
- Láti bẹ̀rẹ̀ àgbékalẹ̀ lójú ẹsẹ̀, tẹ Ṣí tàbí Mú ètò yìí ṣiṣẹ́ láti ipò rẹ ìsinsìnyí
- Láti da ìgbàsílẹ̀ kọ sórí kọ̀ǹpútà rẹ fún àgbékalẹ̀ lọ́jọ́ iwájú, tẹ Ṣàfipamọ́ tàbí Ṣàfipamọ́ ètò yìí sí dísíkì