Trace Id is missing

Àkópọ̀ Èdè Òjísẹ́ (LIP) Windows 8.1

Àkópọ̀ Èdè Òjísẹ́ (LIP) Windows 8.1 ń pèsè ẹ̀yà tí a ṣọ̀tumọ̀ rẹ̀ díẹ̀ ní àwọn àgbègbè tí a ti lo Windows 8.1.

Pàtàkì! Yíyan èdè kan nísàlẹ̀ yìí yóò ṣàyípadà gbogbo àkóónú ojú-ìwé náà sí èdè yẹn.

  • Ẹ̀yà:

    1.0

    Ọjọ́ Àtẹ̀jáde:

    12/11/2013

    Orúkọ Fáìlì:

    LIP_yo-NG-32bit.mlc

    LIP_yo-NG-64bit.mlc

    Ìwọ̀n títóbi Fáìlì:

    2.7 MB

    4.1 MB

    Àkópọ̀ Èdè Òjísẹ́ (LIP) Windows ń pèsè ẹ̀yà tí a ṣọ̀tumọ̀ rẹ̀ díẹ̀ ní àwọn àgbègbè tí a ti lo Windows. Lẹ́yìn tí a ti fisípò tán LIP, àyọkà nínú àwọn onímọ̀, àwọn àpótí àjọsọ, àwọn mẹ́nù, àti àwọn àkọlé Ìrànwọ́ àti Àtìlẹ́yìn ní a máa ṣàfihàn nínú èdè LIP. Àyọkà tí a kò bá túmọ̀ máa wá nínú èdè ìṣàlẹ̀ Windows 8.1. Fún àpẹrẹ, tí o bá ra ẹ̀yà èdè Sípánìṣì ti Windows 8.1, tí o sì ṣàgbékalẹ̀ LIP Katalani kan, àwọn àyọkà kan yóò farahàn ní Sípánìṣì. O le fi jù LIP kan sípò lórí èdè ìsàlẹ̀ kan lọ. A le fi àwọn LIP Windows sípò lórí gbogbo àwọn ẹ̀yà Windows 8.1.
  • Àwọn Ìlànà-iṣẹ́ Ẹ̀rọ tó ní Àtìlẹ́yìn

    Windows 8.1

    • Fún Àmúlò Ẹ̀rọ, ṣíra tẹ̀ níbí

    • Fún àwọn Ìtọ́ni Àkọ́-Físípò, ṣíra tẹ̀ níbí

    1. Ṣíra tẹ bọ́tìnì Gbàsílẹ̀ lórí ojú ìwé láti bẹ̀rẹ̀ gbígbàsílẹ̀, tàbí yan èdè míràn láti àtòjọ jábọ́-sílẹ̀.
    2. Ṣe ọ̀kan nínú àwọn wọ̀nyí:
      • Láti bẹ̀rẹ̀ ìfisípò ní kíá, ṣíra tẹ .
      • Láti ṣàfipamọ́ àgbàsílẹ̀ sí kọ̀ńpútà rẹ fún ìfisípò ní gbà tó báyá, ṣíra tẹ Ṣàfipamọ́
    • Fún Lẹ́yìn àwọn Ìtọ́ni Àkọ́-Físípò, ṣíra tẹ̀ níbí

    • Fún àwọn Ìsòro Tí a mọ̀, ṣíra tẹ̀ níbí