Internet Explorer 11 (32-bit) fún Windows 7 NÌKAN
Internet Explorer yóò dópin, a kí yóò sì ṣàtìlẹ́yìn fún-un mọ́ láti ọjọ́ 15, oṣù Kẹfa, ọdún 2022. Bí ojúlé wẹ́ẹ̀bù yòówù tí o bá lọ bá nílò Internet Explorer, o lè múu ṣàtúnkójọ pẹlú ipò IE nínú Microsoft Edge. Microsoft Edge ni aṣàwákiri tí Microsoft gbani níyànjú láti lò.
Pàtàkì! Yíyan èdè kan nísàlẹ̀ yìí yóò ṣàyípadà gbogbo àkóónú ojú-ìwé náà sí èdè yẹn.
Ẹ̀yà:
11.0.0.4
Ọjọ́ Àtẹ̀jáde:
15/2/2023
Orúkọ Fáìlì:
EIE11_YO-NG_MCM_WIN7.EXE
Ìwọ̀n títóbi Fáìlì:
32.1 MB
- Internet Explorer yóò dópin, a kí yóò sì ṣàtìlẹ́yìn fún-un mọ́ láti ọjọ́ 15, oṣù Kẹfa, ọdún 2022.
- Bí ojúlé wẹ́ẹ̀bù yòówù tí o bá lọ bá nílò Internet Explorer, o lè múu ṣàtúnkójọ pẹlú ipò IE nínú Microsoft Edge. Microsoft Edge ni aṣàwákiri tí Microsoft gbani níyànjú láti lò.
- Fún àlàyé síwájú síi, fún àwọn ìlé-iṣẹ́ tàbí aṣàkóso IT, nípa Internet Explorer 11, jọ̀wọ́
tẹ ibí.
Àwọn Ìlànà-iṣẹ́ Ẹ̀rọ tó ní Àtìlẹ́yìn
Windows 7 Service Pack 1
- Kọmputa/ Aṣètò ìgbésẹ̀: Kọmputa pẹ̀lú aṣètò ìgbésẹ̀ 233MHz tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ (A dámọ̀ràn aṣètò ìgbésẹ̀ Pentium)
- Ààyè ìrántí: 512MB
- Ààyè Awakọ̀ Ẹ̀yà Àfojúrí ti inú:70MB
- Àfihàn: Super VGA (800 x 600) tàbí alabojuto rẹsoluṣọn tó ga pẹ̀lú àwọn àwọ̀ 256.
- Àwọn ẹ̀yà tó ṣeé yọ kúrò: Módẹ̀mù tàbí àsopọ̀ Ayélujára; Máùsì Microsoft, Microsoft IntelliMouse, tàbí ẹ̀rọ àtọ́ka mìíràn tó báamu.
- Láti fi Internet Explorer 11 sórí ẹ̀rọ, tẹ Gbàá láti ayélujára, kí o sì tẹ̀lé àwọn ìtọ́sọ́nà tí ó wà lórí ìbòjú rẹ̀.